Just cant get my mouth off the praises of this so so wonderful God who has given me everything yet asked for nothin..There's nothin that i can ever give that can be worth a fraction of your blessings, a fraction of your love and compassion towards me..Really i dont know what to give and i just wanted to look for a way to praise you..just to say thank you..thank you for everything you have done for me and still continue to do..Lord ,you rock my life..you always do...
p.s...For my peeps who dont understand or cant read what this is all about..im truly sorry..just wanted to do these praises from my roots (The Yoruba Culture).. .I hope you truly understand...
KABIYESI OBA ALAGBARA GIGA,
OBA AWON OBA,
OLORUN AWON OLORUN
ASEDA ORUN
AWAMARIDI
APATA AYERAYE,
ARUGBO OJO
ATOBIJU,
ATOFARATI BI OKE,
ATOBAJAIYE,
ALADE ALAFIA,
ALADE WURA,
AWOLE IRO TIPILETIPILE,
ALAGBADA INA,
ALAWOTELE OORUN,
AWOGBA ARUN MAGBEJE,
ABETI-LU-KARA BI AJERE,
ATAYERO BI AGOGO,
ALAGBEDE ODE ORUN,
ARINU RODE,
OLUMORAN OKAN,
AKIRI SORE,
AFUNNIMA SE REGUN,
APANLA TO SOLE AYERO,
ALEWI-LESE,
ALESE-LEWI,
AKIIKITAN,
AYI-YINTAN,
APE-PETAN,
AWIMAYEHUN,
ALPHA ATI OMEGA,
ADIMULA,
ADIMUYE,
ADESINA TI SINA AIYE F'EDA
A JOBA MATI,
ADAGBA MA PARO OYE
AA JA SEGUNOLU SEGUN,
ALABARO
ADURO GBON IN GBOIN LEYIN ASOTITO
OLU ORUN TI NJE EMI NI
OLUWA AWON OLUWA
OLORUN IMOLE
OLOORE OFE
OGA OGO
OBANGIJI
OLUSO AGUNTAN ENI TIRE
OLOWO GBOGBORO TII Y'OMO RE L'OFIN
OLUTUNU(Comforter)
OLUGBEJA(Defender)
OLUDANDE(Deliverer)
OLUPAMO(Protector)
OLUKONI(Teacher
)OLUPESE(Provider)
OLUBUKUN(Benefactor)
ABIYAMO LOJO IJA
ALATUNSE
ALAABO
A JI DARA
A GB'OMO LOWO IKU
A JI PA JO IKUDA
AJI BORI OSO
AYIPINNU ESU PADA
ATE RERE KARI AYE
AGBENI MA DEYIN
ERU JEJE LETI OKUN PUPA
GBONGBO IDILE JESSE(Root Of Jesse)
EKUN OKO FARAO
AKOO MA TIKA LEHIN
IJINLE IFE
IPINLESE OHUN GBOGBO
OBA IYANU (AWESOME GOD)
IRAWO OWURO
JEHOVAH JIREH
JEHOVAH NISSI
JEHOVAH SHALOM
JEHOVAH SHAMA
JEHOVAH RAPHA
JEHOVAH EL SHADDAI
OLORUN MESHAKI SEDERAKI ATI ABEDNEGO
OLORUN ABRAHAMU, ISAAC ATI JAKOBU
OBA TI N TI ILEKUN TI EDA KAN KO LE SI,
OBA TI SI ILEKUN TI EDA KAN KO LE TI
OBA TO LA OJU AFOJU
OBA TO NJI OKU DIDE
OBA TO POO NI IPA ATI AGABARA
OLORUN OWU (JEALOUS GOD)
OBA TO PA KINIUN LENU MO FUN DANIELI
OBA TO TA OJU ORUN BORA BI ASO
OBA TO FI GBOGBO AGBAYE SE APOTI ITISE RE
OBA TI NLA ONA NIBI TI ONA KO SI
OBA TO MU RIRI JADE NI NU AIRI
OBA IBERE ATI OPIN OHUN GBOGBO
OBA TI I NGBE NI IGA LOJU ANINI LARA
OBA AIKU
OBA AISA
OBA A SORO MA YE
OBA TI KO NI IBERE TI KOSI NI OPIN
KAAABIYESIOOOOOOMIMO! MIMO!! MIMO!!!
Subscribe to:
Post Comments (Atom)
nice one..how long did this take..
ReplyDeletenothin can be too much for the giver of life..
big ups..
Beautiful my dear ...
ReplyDeleteall praise be unto God :-)
Ahh.. completely lost here bro.. At least I know its some form of high level praise singing for God.. Nice..
ReplyDeletethis was really moving..He will be so happy with you :)
ReplyDeleteThanks guys for checkin in.I always appreciate your time and hope to see you drop by soon..
ReplyDelete